ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ta Ni Ọba Rẹ?

Yorùbá
Ta Ni Ọba Rẹ?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022021/univ/art/202022021_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 January ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ta Ni Ọba Rẹ?

Ta Ni Ọba Rẹ?

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ pé kí Sámúẹ́lì yan ọba fún àwọn (1Sa 8:4, 5; it-2 163 ¶1)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ Jèhófà ni ọba (1Sa 8:7, 8; w11 1/1 27 ¶1)

Jèhófa jẹ́ kí wọ́n mọ ohun tó máa jẹ́ àbájáde ohun tí wọ́n béèrè (1Sa 8:9, 18; w10 1/15 30 ¶9)

Jèhófà ni Ọba Aláṣẹ Ayé Àtọ̀run. Ó máa ń mára tu àwọn tó ń ṣàkóso lé lórí, ó sì máa ń buyì kún wọn. Táwa náà bá fara mọ́ ìṣàkóso Jèhófà, ó máa bù kún wa títí láé.

BI ARA Ẹ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè jẹ́ kó hàn nínú ìgbésí ayé mi pé mo fara mọ́ ìṣàkóso Jèhófà?’