ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀

Yorùbá
Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021005/univ/art/202021005_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 January ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀

Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀

A gbọ́dọ̀ pa gbogbo òfin tí Jèhófà fún wa mọ́ (Le 20:22, 23; w04 10/15 11 ¶12)

Jèhófà ṣèlérí pé òun máa fún àwọn èèyàn òun ní ogún (Le 20:24; it-1 1199)

Jèhófà fẹ́ káwọn èèyàn rẹ̀ jẹ́ mímọ́ (Le 20:25, 26; it-1 317 ¶2)

Jèhófà máa ń bù kún àwọn tó bá ní àjọṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú rẹ̀. Tá a bá fẹ́ kínú Ọlọ́run máa dùn sí wa, a gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́, ká sì yàtọ̀ sáwọn èèyàn ayé.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Irú ìtọ́jú wo ni inú Ọlọ́run ò dùn sí tó yẹ kí n yẹra fún?’