ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa

Yorùbá
Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021008/univ/art/202021008_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 January ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa

Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa

Ìrékọjá àti Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú (Le 23:5, 6; it-1 826-827)

Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ (Pẹ́ńtíkọ́sì) (Le 23:15, 16; it-2 598 ¶2)

Àjọyọ̀ Àtíbàbà (Le 23:34; w14 5/15 29 ¶11)

Tá a bá ń ronú lórí ohun tí àjọyọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ́ wa àti bí Ọlọ́run ṣe máa mú àwọn ìlérí rẹ̀ ṣẹ, àá “máa láyọ̀ nígbà gbogbo.”​—Di 16:15.