Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ January 7-13, 2019
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png

January 7-13

ÌṢE 21-22

January 7-13
  • Orin 55 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Kí Ìfẹ́ Jèhófà Ṣẹ”: (10 min.)

    • Iṣe 21:8-12​—Àwọn Kristẹni kan ń rọ Pọ́ọ̀lù pé kó má ṣe lọ sí Jerúsálẹ́mù torí ewu tó ń dúró dè é níbẹ̀ (bt 177-178 ¶15-16)

    • Iṣe 21:13​—Pọ́ọ̀lù pinnu pé ìfẹ́ Jèhófà lòun máa ṣe (bt 178 ¶17)

    • Iṣe 21:14​—Nígbà tí àwọn ará rí i pé Pọ́ọ̀lù ò yí ìpinnu rẹ̀ pa dà, wọ́n fara mọ́ ìpinnu tó ṣe (bt 178 ¶18)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 21:​23, 24​—Tó bá jẹ́ pé lóòótọ́ làwọn Kristẹni ò sí lábẹ́ Òfin Mósè mọ́, kí nìdí tí àwọn alàgbà tó wà ní Jerúsálẹ́mù fi fún Pọ́ọ̀lù ní ìtọ́ni yìí? (bt 184-185 ¶10-12)

    • Iṣe 22:16​—Báwo ni Pọ́ọ̀lù ṣe lè wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ nù? (“wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ nù nípa kíké tí o bá ń ké pe orúkọ rẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 22:16, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 21:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5) *

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

^ ìpínrọ̀ 15 ^ ìpínrọ̀ 18 Àkíyèsí: Bẹ̀rẹ̀ láti oṣù yìí, yàtọ̀ sí ìtọ́ni tí akẹ́kọ̀ọ́ kọ̀ọ̀kan máa tẹ̀ lé, a tún máa kọ kókó tó máa ṣiṣẹ́ lé lórí nínú ìwé pẹlẹbẹ Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni (th) sínú àkámọ́.