Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ January 28–February 3, 2019
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

January 28–February 3

ÌṢE 27-28

January 28–February 3
  • Orin 129 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Pọ́ọ̀lù Wọkọ̀ Ojú Omi Lọ sí Róòmù”: (10 min.)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 27:9​—Kí ni “ààwẹ̀ [ọjọ́ ètùtù]”? (“ààwẹ̀ [ọjọ́ ètùtù]” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 27:9, nwtsty)

    • Iṣe 28:11​—Kí ló gbàfiyèsí nípa ère tó wà lórí ọkọ̀ yẹn? (“Àwọn Ọmọ Súúsì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 28:11, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 27:​1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI