Alábòójútó àyíká kan àti ìyàwó rẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn ní orílẹ̀-èdè Faransé, lọ́dún 1957

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI January 2019

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí bá a ṣe lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Kí Ìfẹ́ Jèhófà Ṣẹ”

Tẹ́nì kan bá fẹ́ yááfì àwọn nǹkan kan, kó bàa lè ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà, a ò gbọ́dọ̀ gbìyànjú láti paná ìtara tó ní.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Ló Bá Wa Tọ́ Àwọn Ọmọ Wa

Ṣé ò ń tẹ̀ lé àwọn ìmọ̀ràn Ọlọ́run lórí bó o ṣe lè tọ́ àwọn ọmọ rẹ yanjú?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Wọ́n Fẹ̀sùn Kan Pọ́ọ̀lù Pé Alákòóbá Ni àti Pé Ó Ń Ru Ìdìtẹ̀ Sókè

Ìbátan Pọ́ọ̀lù kan ni kò jẹ́ kí wọ́n pa Pọ́ọ̀lù. Kí ni ìtàn yìí kọ́ wa?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà

Tí àwọn tó ń ta kò wá bá “fi àṣẹ àgbékalẹ̀ dáná ìjàngbọ̀n,” báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec

Wo bí wọ́n ṣe gbèjà ìhìn rere ní Quebec.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Pọ́ọ̀lù Wọkọ̀ Ojú Omi Lọ sí Róòmù

Nígbà tí Pọ́ọ̀lù wà lẹ́wọ̀n, ṣe ló ń wàásù ìhìn rere fáwọn èèyàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Pọ́ọ̀lù Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Ọlọ́run Ó sì Mọ́kànle”

Nígbà míì tí àwọn alábòójútó àyíká bá wá sí ìjọ yín, kí lo lè ṣe láti ràn wọ́n lọ́wọ́ kí wọ́n lè mọ́kàn le?