Yorùbá
“Onídàájọ́ Gbogbo Ayé” Pa Sódómù àti Gòmórà Run
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202020049/univ/art/202020049_univ_sqr_xl.jpg
mwb20 February ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 18-19

“Onídàájọ́ Gbogbo Ayé” Pa Sódómù àti Gòmórà Run

“Onídàájọ́ Gbogbo Ayé” Pa Sódómù àti Gòmórà Run

18:23-25, 32; 19:24, 25

Kí la rí kọ́ látinú ohun tí Jèhófà ṣe sáwọn ará ìlú Sódómù àti Gòmórà?

  • Jèhófà ò ní gbà káwọn ẹni burúkú máa hùwà ìkà títí lọ

  • Àwọn tó bá ń fetí sí àṣẹ Jèhófà, tí wọ́n sì ń pa á mọ́ ló máa la ìparun tó ń bọ̀ já.​—Lk 17:28-30

BI ARA RẸ PÉ: ‘Ṣé ìwà àìnítìjú táwọn èèyàn ayé ń hù máa ń kó mi nírìíra?’ (2Pe 2:7) ‘Ṣé ó hàn nínú gbogbo ohun tí mò ń ṣe pé ìfẹ́ Jèhófà ló gbà mí lọ́kàn?’