ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI February 2020
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Ìjíròrò tó dá lórí ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú àti bí Ọlọ́run ṣe máa mú àwọn ìlérí rẹ̀ ṣẹ.
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Májẹ̀mú Kan Tó Kàn Ẹ́
Ìbùkún wo là ń retí nípasẹ̀ ìlérí tí Jèhófà ṣe fún Ábúráhámù lọ́pọ̀ ọdún sẹ́yìn?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Kí Ló Lè Rí Kọ́ Nínú Àwọn Orin Wa Míì?
Àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì wo làwọn orin yìí kọ́ wa?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Kí Nìdí Tí Jèhófà Fi Yí Orúkọ Ábúrámù àti Sáráì Pa Dà?
Bíi ti Ábúrámù àti Sáráì, báwo lo ṣe lè ṣe orúkọ rere fún ara rẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Bí Àwọn Tọkọtaya Ṣe Lè Túbọ̀ Ṣe Ara Wọn Lọ́kan
Báwo ni àpẹẹrẹ Ábúráhámù àti Sérà ṣe lè ran àwọn tọkọtaya lọ́wọ́ kí wọ́n lè túbọ̀ ṣe ara wọn lọ́kan?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Onídàájọ́ Gbogbo Ayé” Pa Sódómù àti Gòmórà Run
Ẹ̀kọ́ wo ni ìparun Sódómù àti Gòmórà kọ́ àwọn èèyàn lóde òní?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Látinú Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́?
Báwo lo ṣe lè jàǹfààní nínú bó o ṣe ń ṣàyẹ̀wò Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lójoojúmọ́?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Gbogbo Ìgbà Ni Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ
Bá a bá ronú lórí bí Jèhófà ṣe mú ìlérí rẹ̀ ṣe fún Ábúráhámù àti Sérà, báwo nìyẹn ṣe lè mú kí ìgbàgbọ́ wa túbọ̀ lágbára?

