Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ February 4-​10, 2019
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png

February 4-​10

RÓÒMÙ 1-3

February 4-​10
  • Orin 88 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà, Sọ̀rọ̀ Bí Ẹni Ń Báni Fọ̀rọ̀ Wérọ̀, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 2 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w06 6/1 12-13​—Àkòrí: Máa Rántí Pé Ó Níbi Tágbára Rẹ àti Tàwọn Míì Mọ. (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI