Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ December 21-27, 2020
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 December ojú ìwé 5

December 21-27

LÉFÍTÍKÙ 14-15

December 21-27
  • Orin 122 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ìjọsìn Mímọ́ Gba Pé Kéèyàn Wà ní Mímọ́”: (10 min.)

    • Le 15:13-15​—Àwọn ọkùnrin gbọ́dọ̀ wẹ ara wọn mọ́ (it-1 263)

    • Le 15:28-30​—Àwọn obìnrin gbọ́dọ̀ wẹ ara wọn mọ́ (it-2 372 ¶2)

    • Le 15:31​—Jèhófà fẹ́ kí ìjọsìn wa jẹ́ mímọ́ (it-1 1133)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Le 14:14, 17, 25, 28​—Kí la rí kọ́ látinú ohun tí ẹni tó ní àrùn ẹ̀tẹ̀ gbọ́dọ̀ ṣe kó tó lè wà ní mímọ́? (it-1 665 ¶5)

    • Le 14:43-45​—Kí ni òfin tó wà nípa ilé tó ní àrùn ẹ̀tẹ̀ tó le gan-an kọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa Jèhófà? (g 1/06 14, àpótí)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 14:​1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI