ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Jọ Ẹ́ Lójú Bíi Ti Jèhófà

Yorùbá
Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Jọ Ẹ́ Lójú Bíi Ti Jèhófà
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202020293/univ/art/202020293_univ_sqr_xl.jpg
mwb20 August ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 21-22

Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Jọ Ẹ́ Lójú Bíi Ti Jèhófà

Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Jọ Ẹ́ Lójú Bíi Ti Jèhófà

21:20, 22, 23, 28, 29

Ẹ̀mí ṣeyebíye gan-an lójú Jèhófà. Báwo làwa náà ṣe lè fi hàn pé ẹ̀mí jọ wá lójú?

  • Nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn látọkànwá, kó o sì máa bọ̀wọ̀ fún wọn.​—Mt 22:39; 1Jo 3:15

  • Fi kún ìtara ẹ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù kó lè hàn pé o nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn lóòótọ́.​—1Kọ 9:​22, 23; 2Pe 3:9

  • Fi hàn pé ọ̀rọ̀ ààbò jẹ ẹ́ lógún.​—Owe 22:3

Tí ẹ̀mí bá jọ wá lójú, báwo nìyẹn ò ṣe ní jẹ́ ká jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀?