ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

“Ẹ Dúró Gbọn-in, Kí Ẹ sì Rí Bí Jèhófà Ṣe Máa Gbà Yín Là”

Yorùbá
“Ẹ Dúró Gbọn-in, Kí Ẹ sì Rí Bí Jèhófà Ṣe Máa Gbà Yín Là”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202020283/univ/art/202020283_univ_sqr_xl.jpg
mwb20 August ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 13-14

“Ẹ Dúró Gbọn-in, Kí Ẹ sì Rí Bí Jèhófà Ṣe Máa Gbà Yín Là”

“Ẹ Dúró Gbọn-in, Kí Ẹ sì Rí Bí Jèhófà Ṣe Máa Gbà Yín Là”

14:13, 14, 21, 22, 26-28

Jèhófà máa ń gba tẹni rò tó bá ń gbani là. Báwo ló ṣe gba tàwọn ọmọ Ísírẹ́lì rò nígbà tó mú wọn jáde kúrò ní Íjíbítì?

Kí ló dá wa lójú bí ìpọ́njú ńlá ṣe túbọ̀ ń sún mọ́lé?​—Ais 30:15