ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ August 10-16, 2020

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ August 10-16, 2020
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 August ojú ìwé 4

August 10-16

Ẹ́KÍSÓDÙ 15-16

August 10-16
  • Orin 149 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Máa Fi Orin Yin Jèhófà”: (10 min.)

    • Ẹk 15:​1, 2​—Mósè àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi orin yin Jèhófà (w95 10/15 11 ¶11)

    • Ẹk 15:​11, 18​—Ó yẹ ká máa yin Jèhófà (w95 10/15 11-12 ¶15-16)

    • Ẹk 15:​20, 21​—Míríámù àtàwọn obìnrin Ísírẹ́lì fi orin yin Jèhófà (it-2 454 ¶1; 698)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 16:13​—Kí ló ṣeé ṣe kó fà á tí Jèhófà fi fi ẹyẹ àparò bọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní aginjù? (w11 9/1 14)

    • Ẹk 16:​32-34​—Ibo ni wọ́n tọ́jú ìkòkò mánà sí? (w06 1/15 31)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 16:​1-18 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI