ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu

Yorùbá
Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202019289/univ/art/202019289_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 1-3

Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu

Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu

1:9

Jésù nífẹ̀ẹ́ òdodo, ó sì kórìíra ohunkóhun tó máa múnú bí Jèhófà.

Báwo làwa náà ṣe lè nífẹ̀ẹ́ òdodo bíi ti Jésù . . .

  • nígbà tá a bá dojú kọ ìdẹwò láti wo ìṣekúṣe?

  • tí wọ́n bá yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́ nínú ìdílé mi?