Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ August 6-12, 2018
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

August 6-12

Lúùkù 17-18

August 6-12
  • Orin 18 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Máa Dúpẹ́ Oore”: (10 min.)

    • Lk 17:​11-14​—Jésù wo àwọn adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá sàn (“àwọn ọkùnrin adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá,” “Glossary Ẹ̀tẹ̀; Adẹ́tẹ̀,” Mt 8:2; adẹ́tẹ̀,” “lọ fi ara rẹ han àlùfáà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 17:12, 14, nwtsty)

    • Lk 17:​15, 16​—Ọ̀kan lára àwọn adẹ́tẹ̀ náà ló pa dà wá dúpẹ́ lọ́wọ́ Jésù

    • Lk 17:​17, 18​—Ìtàn yìí jẹ́ ká rí ìdí tó fi yẹ ká máa dúpẹ́ oore (w08 8/1 14-15 ¶8-9)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Lk 17:​7-10​—Kí ni Jésù fẹ́ fà yọ nínú àpèjúwe yìí? (“tí kò dára fún ohunkóhun” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 17:10, nwtsty)

    • Lk 18:8​—Irú ìgbàgbọ́ wo ni Jésù ń sọ nínú ẹsẹ yìí? (“ìgbàgbọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 18:8, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 18:​24-43

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI