ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ṣe Tán Láti Dárí Jini

Yorùbá
Ṣe Tán Láti Dárí Jini
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202018291/univ/art/202018291_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 23-24

Ṣe Tán Láti Dárí Jini

Ṣe Tán Láti Dárí Jini

24:34

Ta ni mo gbọ́dọ̀ dárí jì?

Kí ni gbólóhùn náà “ṣe tán láti dárí jini” túmọ̀ sí? (Sm 86:5) Jèhófà àti Ọmọ rẹ̀ máa ń kíyè sí ọkàn ẹni tó bá dẹ́ṣẹ̀ tó sì wá yí pa dà, kí wọ́n lè dárí jì í.