ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Iṣẹ́ Ńlá Ni Iṣẹ́ Olùṣọ́

Yorùbá
Iṣẹ́ Ńlá Ni Iṣẹ́ Olùṣọ́
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202017287/univ/art/202017287_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 32-34

Iṣẹ́ Ńlá Ni Iṣẹ́ Olùṣọ́

Iṣẹ́ Ńlá Ni Iṣẹ́ Olùṣọ́

Àwọn olùṣọ́ sábà máa ń dúró sórí ògiri ìlú tàbí òkè ilé gíga kí wọ́n lè tètè kìlọ̀ fáwọn ará ìlú tí nǹkan aburú bá fẹ́ wọ inú ìlú. Jèhófà yan Ìsíkíẹ́lì lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ láti jẹ́ ‘olùṣọ́ fún ilé Ísírẹ́lì.’

  • 33:7

    Ìsíkíẹ́lì kìlọ̀ fún àwon ọmọ Ísírẹ́lì pé Ọlọ́run máa fìyà jẹ wọ́n tí wọn kò bá yí pa dà

    Ọ̀rọ̀ Jèhófà wo là ń kéde fún aráyé lónìí?

  • 33:9, 14-16

    Bí Ìsíkíẹ́lì bá kìlọ̀ fún àwọn èèyàn náà, ó máa gba ẹ̀mí wọn àti ti ara rẹ̀ là

    Kí ló yẹ kó sún wa láti máa kéde ọ̀rọ̀ Jèhófà ní kánjúkánjú báyìí?