ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 92-101 Bí Àwọn Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó TẸ̀ Ẹ̣́ Bí Àwọn Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó 92:12 Igi ọ̀pẹ máa ń lo ju ọgọ́rùn-ún ọdún lọ láyé, síbẹ̀ á ṣì máa so èso Àwọn àgbàlagbà máa ń so èso tẹ̀mí nígbà tí wọ́n bá ń . . . 92:13-15 gbàdúrà fún àwọn ẹlòmíì kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ sáwọn ìpàdé ìjọ tí wọ́n sì ń kópa níbẹ̀ sọ àwọn ìrírí tí wọ́n ní fún àwọn ẹlòmíì wàásù tọkàntọkàn Pa Dà Èyí Tó Kàn O Tún Lè Wo Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà (àwọn orin wa míì) Máa Bọ̀wọ̀ Fáwọn Àgbàlagbà Kí lo lè ṣe táá fi hàn pé o bọ̀wọ̀ fáwọn àgbàlagbà tó ti ń fi ọ̀pọ̀ ọdún sin Jèhófà?