Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 14-16

Ọlọ́run Máa Di “Ohun Gbogbo fún Kálukú”

Ọlọ́run Máa Di “Ohun Gbogbo fún Kálukú”

15:​24-28

Ọjọ́ ọ̀la ológo ló ń dúró de àwọn tó bá jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà. Àwọn ìlérí Jèhófà máa túbọ̀ jinlẹ̀ lọ́kàn wa tá a bá ń fi ìtara sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ fún àwọn míì. Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ fún àwọn ará pé kí wọ́n ronú lórí bí nǹkan ṣe máa rí ní òpin Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso Kristi, nígbà tí Jèhófà máa di “ohun gbogbo fún kálukú.”

Èwo nínú àwọn ìlérí tá à ń retí yìí ló wọ̀ ẹ́ lọ́kàn jù lọ, kí sì nìdí?

Kí ló jẹ́ kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run máa ṣe àwọn nǹkan tó ṣèlérí?