ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?

Yorùbá
Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202018125/univ/art/202018125_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 27-28

Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?

Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?

28:18-20

Kí Nìdí? Jèhófà fún Jésù ní ọlá àṣẹ tó gbòòrò gan-an

Níbo? Jésù pàṣẹ fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ pé kí wọ́n sọ “àwọn ènìyàn gbogbo orílẹ̀-èdè” di ọmọ ẹ̀yìn

A ó máa bá a lọ láti kọ́ àwọn èèyàn kí wọ́n lè máa pa gbogbo ohun tí Jésù ti pa láṣẹ fún wa mọ́

  • Báwo la ṣe ń kọ́ àwọn ẹlòmíì ní àṣẹ Jésù?

  • Báwo la ṣe lè ran ẹni tí à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ láti fi ẹ̀kọ́ Jésù sílò?

  • Báwo la ṣe lè ran ẹni tí à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ láti máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù?