Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 5-6

Jésù Ní Agbára Láti Jí Àwọn Èèyàn Wa Tó Kú Dìde

Jésù Ní Agbára Láti Jí Àwọn Èèyàn Wa Tó Kú Dìde

5:38-42

  • Tá a bá sunkún nígbà tí èèyàn wa bá kú, ìyẹn ò fi hàn pé a ò ní ìgbàgbọ́ nínú àjíǹde (Jẹ 23:2)

  • A máa túbọ̀ nígbàgbọ́ nínú àjíǹde tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú, tá a bá ń ronú lórí àwọn àjíǹde tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀

Ta lò ń fojú sọ́nà láti rí nígbà àjíǹde?

Báwo ló ṣe máa rí lára ẹ tẹ́ ẹ bá pa dà ríra?