ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìyàtọ̀ àti Ìjọra Tó Wà Láàárín Ìrékọjá àti Ìrántí Ikú Kristi

Yorùbá

https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202018123/univ/art/202018123_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 26

Ìyàtọ̀ àti Ìjọra Tó Wà Láàárín Ìrékọjá àti Ìrántí Ikú Kristi

Ìyàtọ̀ àti Ìjọra Tó Wà Láàárín Ìrékọjá àti Ìrántí Ikú Kristi

26:18

Kọ orúkọ àwọn nǹkan tá a fi nọ́ńbà sí.

Èwo nínú àwọn nǹkan yìí là ń lò fún Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa?