ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní April 2018

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní April 2018
/assets/ct/579af9cf16/images/syn_placeholder_sqr.png

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ibo la ti lè rí ìmọ̀ràn gidi nípa bá a ṣe lè máa gbé ìgbé ayé aláyọ̀?

Bíbélì: Sm 1:​1, 2

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Tá a bá nífẹ̀ẹ́ owó, tá a sì ní ohun ìní tó pọ̀, ṣé ó máa fún wa láyọ̀?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Tá a bá nífẹ̀ẹ́ owó, tá a sì ní ohun ìní tó pọ̀, ṣé ó máa fún wa láyọ̀?

Bíbélì: 1Ti 6:​9, 10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tí kò fi dáa kéèyàn máa ronú jù nípa àwọn ìṣòro tó ní?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí nìdí tí kò fi dáa kéèyàn máa ronú jù nípa àwọn ìṣòro tó ní?

Bíbélì: Owe 17:22

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ìdílé kan ṣe lè ṣàṣeyọrí láìka àwọn ìṣòro wọn sí?