Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

April 3-9

JEREMÁYÀ 17-21

April 3-9
 • Orin 69 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Darí Èrò àti Ìṣe Rẹ”: (10 min.)

  • Jer 18:1-4—Àrà tó bá wu amọ̀kòkò ló lè fi amọ̀ dá (w99 4/1 22 ¶3)

  • Jer 18:5-10—Jèhófà ní àṣẹ lórí àwa èèyàn (it-2 776 ¶4)

  • Jer 18:11—Jẹ́ amọ̀ tí ó rọ̀ lọ́wọ́ Jèhófà (w99 4/1 22 ¶4-5)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 17:9—Báwo la ṣe lè mọ̀ tí ọkàn ẹnì kan bá ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe àdàkàdekè? (w01 10/15 25 ¶13)

  • Jer 20:7—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà lo okun rẹ̀ lórí Jeremáyà tó sì tàn án? (w07 3/15 9 ¶6)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 21:3-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI