Ṣé o ṣì máa rí àwọn èèyàn ẹ tó ti kú?
“Wákàtí náà ń bọ̀, tí gbogbo àwọn tó wà nínú ibojì ìrántí máa gbọ́ ohùn rẹ̀, tí wọ́n á sì jáde wá.”—Jòhánù 5:28, 29.
Bíbélì jẹ́ kó dá wa lójú pé
-
Ọlọ́run máa jí àwọn èèyàn wa tó ti kú dìde.—Ìṣe 24:15.
-
Ó wù ú gan-an láti jí wọn dìde.—Jóòbù 14:13-15.
Kó o lè mọ púpọ̀ sí i, lọ sí jw.org/yo.

