Báwo ni ìdílé rẹ ṣe lè láyọ̀?

Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?

Yorùbá
Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102024303/afrn/art/1102024303_afrn_sqr_xl.jpg
T-fam ojú ìwé 1-2

Báwo ni ìdílé rẹ ṣe lè láyọ̀?

Báwo ni ìdílé rẹ ṣe lè láyọ̀?

“Kálukú yín gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ aya rẹ̀ bó ṣe nífẹ̀ẹ́ ara rẹ̀; bákan náà, kí aya ní ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀ fún ọkọ rẹ̀.”—Éfésù 5:33.

Bíbélì sọ pé

  • Ọkọ àti aya ò gbọ́dọ̀ dalẹ̀ ara wọn.—Mátíù 19:4-6.

  • Táwọn ọmọ bá ń bọ̀wọ̀ fáwọn òbí wọn, tí wọ́n sì ń gbọ́ràn sí wọn lẹ́nu, ayé wọn máa dáa.—Éfésù 6:1-3.

Kó o lè mọ púpọ̀ sí i, lọ sí jw.org/yo.