Yorùbá
Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú​—Apá Kìíní
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102019289/univ/art/1102019289_univ_sqr_xl.jpg

Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú​—Apá Kìíní

Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú​—Apá Kìíní

Inú ìlú tí wọ́n ti pa Jèhófà tì ní Jòsáyà dàgbà sí, èyí tó pọ̀ jù lára àwọn ìlú náà ló sì ń sin Báálì. Ṣé tiẹ̀ máa wá dá yàtọ̀ ni, ṣé á lè dúró lórí ìpinnu ẹ̀ láti ṣé ohun tó tọ́?