Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú—Apá Kejì
Pẹ̀lú gbogbo bí wọ́n ṣe ń halẹ̀, tí wọ́n sì ń ta ko Ọba Jòsáyà, síbẹ̀ ó dúró lórí ìpinnu ẹ̀ láti mú ìbọ̀rìṣà kúrò nílùú pátápátá, ó tún ran àwọn aráàlú lọ́wọ́ láti nífẹ̀ẹ́ Jèhófà kí wọ́n sì máa ṣe ohun tó tọ́.

