Ẹ̀KỌ́ 1 Ìnasẹ̀ Ọ̀rọ̀ Tó Dára TẸ̀ Ẹ̣́ Ìnasẹ̀ Ọ̀rọ̀ Tó Dára Kí lo lè ṣe tó máa jẹ́ kó wu àwọn tó o fẹ́ bá sọ̀rọ̀ láti gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ? Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Pa Dà Èyí Tó Kàn O Tún Lè Wo TẸRA MỌ́ KÍKÀWÉ ÀTI KÍKỌ́NI Kíkàwé àti Kíkọ́ni—Ìnasẹ̀ Ọ̀rọ̀ Tó Dára Iṣẹ́ méjì ni ìnasẹ̀ ọ̀rọ̀ tó dára máa ń ṣe.