Jèhófà Ń Darí Wa ní Ọ̀nà Àlàáfíà
Ọjọ́ pẹ́ tí Jèhófà ti ń darí àwọn èèyàn ẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ló sì ń fìdí Ìjọba rẹ̀ múlẹ̀.
Jèhófà Ń Darí Wa ní Ọ̀nà Àlàáfíà—Apá 1
Kí nìdí tó fi dá wa lójú pé Jèhófà máa pèsè fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó bá gbẹ́kẹ̀ lé e lónìí?
Jèhófà Ń Darí Wa ní Ọ̀nà Àlàáfíà—Apá 2
Kí ló mú kó dá wa lójú pé a máa tó ní àlàáfíà tí ò lópin?

