Yorùbá
Àwọn Ìṣẹ̀dá Ọlọ́run Ń Fi Ògo Rẹ̀ Hàn—Àwọn Ohun Abẹ̀mí Ń Ṣiṣẹ́ Pọ̀
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102017894/univ/art/1102017894_univ_sqr_xl.jpg

Àwọn Ohun Abẹ̀mí Ń Ṣiṣẹ́ Pọ̀

Àwọn Ohun Abẹ̀mí Ń Ṣiṣẹ́ Pọ̀

Àwọn ohun tó wà láyé ńkọ́? Ṣé ẹ̀rí wà pé gbogbo nǹkan alààyè ni ètò wà fún àti pé ńṣe ni gbogbo wọn ń ṣiṣẹ́ pọ̀?