“Jèhófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé”
Wo bí Hesekáyà ṣe borí ìṣòro lọ́tùn-lósì kó lè ṣe ìpinnu tó dá lórí ìgbàgbọ́ àti ìdúróṣinṣin, tó sì tipa bẹ́ẹ̀ fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ fáwọn ọmọ ìlú rẹ̀ àwọn gbogbo àwọn tó ń sin Jèhófà lónìí.
O Tún Lè Wo
FÌGBOYÀ ṢE OHUN TÍ ỌLỌ́RUN FẸ́
Jèhóádà—Ó Dáàbò Bo Ọba
Àwọn nǹkan wo ni Jèhóádà ṣe tó fi hàn pé ó nígboyà? Àwọn ọ̀nà wo lo lè gbà fi hàn pé o nígboyà bíi ti Jèhóádà?
ÌWÉ ÌTÀN BÍBÉLÌ
Ọlọ́run Ran Hesekáyà Ọba Lọ́wọ́
Ní òrú ọjọ́ kan, áńgẹ́lì kan pa 185,000 ọmọ ogun Ásíríà.

