Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àkọsílẹ̀ Ìhìn Rere Mátíù

Orí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

 • 1

  • Ìlà ìdílé Jésù Kristi (1-17)

  • Ìbí Jésù (18-25)

 • 2

  • Àwọn awòràwọ̀ wá (1-12)

  • Wọ́n sá lọ sí Íjíbítì (13-15)

  • Hẹ́rọ́dù pa àwọn ọmọdékùnrin (16-18)

  • Wọ́n pa dà sí Násárẹ́tì (19-23)

 • 3

  • Jòhánù Arinibọmi ń wàásù (1-12)

  • Jésù ṣe ìrìbọmi (13-17)

 • 4

  • Èṣù dán Jésù wò (1-11)

  • Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù ní Gálílì (12-17)

  • Ó pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn àkọ́kọ́ (18-22)

  • Jésù ń wàásù, ó ń kọ́ni, ó sì ń woni sàn (23-25)

 • 5

  • ÌWÀÁSÙ ORÍ ÒKÈ (1-48)

   • Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ni lórí òkè (1, 2)

   • Ohun mẹ́sàn-án tó ń múni láyọ̀ (3-12)

   • Iyọ̀ àti ìmọ́lẹ̀ (13-16)

   • Jésù máa mú Òfin ṣẹ (17-20)

   • Ìmọ̀ràn lórí ìbínú (21-26), àgbèrè (27-30), ìkọ̀sílẹ̀ (31, 32), ìbúra (33-37), ẹ̀san (38-42), nínífẹ̀ẹ́ àwọn ọ̀tá (43-48)

 • 6

  • ÌWÀÁSÙ ORÍ ÒKÈ (1-34)

   • Má ṣe òdodo àṣehàn (1-4)

   • Bí o ṣe lè gbàdúrà (5-15)

    • Àdúrà àwòkọ́ṣe (9-13)

   • Ààwẹ̀ (16-18)

   • Ìṣúra ní ayé àti ọ̀run (19-24)

   • Ẹ má ṣàníyàn mọ́ (25-34)

    • Ẹ máa wá Ìjọba náà lákọ̀ọ́kọ́ (33)

 • 7

  • ÌWÀÁSÙ ORÍ ÒKÈ (1-27)

   • Ẹ yéé dáni lẹ́jọ́ (1-6)

   • Ẹ máa béèrè, ẹ máa wá kiri, ẹ máa kan ilẹ̀kùn (7-11)

   • Òfin Oníwúrà (12)

   • Ẹnubodè tóóró (13, 14)

   • Àwọn èso wọn la máa fi mọ̀ wọ́n (15-23)

   • Ilé orí àpáta, ilé orí iyanrìn (24-27)

  • Bí Jésù ṣe ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ ya àwọn èrò lẹ́nu (28, 29)

 • 8

  • Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn (1-4)

  • Ọ̀gágun fi hàn pé òun nígbàgbọ́ (5-13)

  • Jésù wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn ní Kápánáúmù (14-17)

  • Bí a ṣe lè tẹ̀ lé Jésù (18-22)

  • Jésù mú kí ìjì dáwọ́ dúró (23-27)

  • Jésù lé àwọn ẹ̀mí èṣù lọ sínú àwọn ẹlẹ́dẹ̀ (28-34)

 • 9

  • Jésù wo alárùn rọpárọsẹ̀ sàn (1-8)

  • Jésù pe Mátíù (9-13)

  • Ìbéèrè nípa ààwẹ̀ gbígbà (14-17)

  • Ọmọbìnrin Jáírù; obìnrin kan fọwọ́ kan aṣọ àwọ̀lékè Jésù (18-26)

  • Jésù wo afọ́jú àti ẹni tí kò lè sọ̀rọ̀ sàn (27-34)

  • Ìkórè pọ̀, àmọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ò tó nǹkan (35-38)

 • 10

  • Àwọn àpọ́sítélì méjìlá (1-4)

  • Ìtọ́ni tó wà fún iṣẹ́ ìwàásù (5-15)

  • Wọ́n máa ṣe inúnibíni sí àwọn ọmọ ẹ̀yìn (16-25)

  • Ẹ bẹ̀rù Ọlọ́run, ẹ má bẹ̀rù èèyàn (26-31)

  • Mo wá láti mú idà wá, kì í ṣe àlàáfíà (32-39)

  • Gbígba àwọn ọmọ ẹ̀yìn (40-42)

 • 11

  • Ó yin Jòhánù Arinibọmi (1-15)

  • Ó dẹ́bi fún ìran aláìgbọràn (16-24)

  • Jésù yin Bàbá rẹ̀ torí pé ó ṣojúure sí àwọn tó rẹlẹ̀ (25-27)

  • Àjàgà Jésù ń tuni lára (28-30)

 • 12

  • Jésù ni “Olúwa Sábáàtì” (1-8)

  • Ó wo ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ sàn (9-14)

  • Ìránṣẹ́ tí Ọlọ́run fẹ́ràn (15-21)

  • Ó fi ẹ̀mí mímọ́ lé ẹ̀mí èṣù jáde (22-30)

  • Ẹ̀ṣẹ̀ tí kò ní ìdáríjì (31, 32)

  • Èso igi la fi máa mọ̀ ọ́n (33-37)

  • Àmì Jónà (38-42)

  • Tí ẹ̀mí àìmọ́ bá pa dà wá (43-45)

  • Ìyá Jésù àtàwọn arákùnrin rẹ̀ (46-50)

 • 13

  • ÀWỌN ÀPÈJÚWE NÍPA ÌJỌBA NÁÀ (1-52)

   • Afúnrúgbìn (1-9)

   • Ìdí tí Jésù fi lo àwọn àpèjúwe (10-17)

   • Ó sọ ìtumọ̀ àpèjúwe afúnrúgbìn (18-23)

   • Àlìkámà àti èpò (24-30)

   • Hóró músítádì àti ìwúkàrà (31-33)

   • Bó ṣe lo àwọn àpèjúwe mú àsọtẹ́lẹ̀ ṣẹ (34, 35)

   • Ó sọ ìtumọ̀ àpèjúwe àlìkámà àti èpò (36-43)

   • Ìṣúra tó pa mọ́ àti péálì tó dáa (44-46)

   • Àwọ̀n (47-50)

   • Ìṣúra tuntun àti ti àtijọ́ (51, 52)

  • Wọn ò gba Jésù ní agbègbè ìlú rẹ̀ (53-58)

 • 14

  • Wọ́n gé orí Jòhánù Arinibọmi (1-12)

  • Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (13-21)

  • Jésù rìn lórí omi (22-33)

  • Ó ṣèwòsàn ní Jẹ́nẹ́sárẹ́tì (34-36)

 • 15

  • Ó tú àṣírí àwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ (1-9)

  • Inú ọkàn ni ohun tó ń sọni di aláìmọ́ ti ń wá (10-20)

  • Ìgbàgbọ́ obìnrin ará Foníṣíà lágbára gan-an (21-28)

  • Jésù wo ọ̀pọ̀ àìlera sàn (29-31)

  • Jésù bọ́ 4,000 èèyàn (32-39)

 • 16

  • Wọ́n ń wá àmì (1-4)

  • Ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí (5-12)

  • Àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba náà (13-20)

   • A kọ́ ìjọ sórí àpáta (18)

  • Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú Jésù (21-23)

  • Bí a ṣe lè jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn tòótọ́ (24-28)

 • 17

  • Ìyípadà ológo (1-13)

  • Ìgbàgbọ́ bíi hóró músítádì (14-21)

  • Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (22, 23)

  • Wọ́n fi owó ẹnu ẹja san owó orí (24-27)

 • 18

  • Ẹni tó tóbi jù nínú Ìjọba náà (1-6)

  • Àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀ (7-11)

  • Àpèjúwe àgùntàn tó sọ nù (12-14)

  • Bí o ṣe lè jèrè arákùnrin (15-20)

  • Àpèjúwe ẹrú tí kò dárí jini (21-35)

 • 19

  • Ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ (1-9)

  • Ẹ̀bùn wíwà láìlọ́kọ tàbí láìláya (10-12)

  • Jésù súre fún àwọn ọmọdé (13-15)

  • Ìbéèrè ọ̀dọ́kùnrin ọlọ́rọ̀ (16-24)

  • Àwọn ohun tí a fi sílẹ̀ nítorí Ìjọba náà (25-30)

 • 20

  • Àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà gba iye owó kan náà (1-16)

  • Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (17-19)

  • Wọ́n ń wá ipò nínú Ìjọba náà (20-28)

   • Jésù fi ẹ̀mí rẹ̀ ṣe ìràpadà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn (28)

  • Ó wo ọkùnrin afọ́jú méjì sàn (29-34)

 • 21

  • Jésù wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ (1-11)

  • Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (12-17)

  • Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́ (18-22)

  • Wọ́n béèrè àṣẹ tí Jésù fi ń ṣe nǹkan (23-27)

  • Àpèjúwe àwọn ọmọ méjì (28-32)

  • Àpèjúwe àwọn tó ń dáko, tí wọ́n sì pààyàn (33-46)

   • Wọ́n pa olórí òkúta igun ilé tì (42)

 • 22

  • Àpèjúwe ayẹyẹ ìgbéyàwó (1-14)

  • Ọlọ́run àti Késárì (15-22)

  • Ìbéèrè nípa àjíǹde (23-33)

  • Àṣẹ méjì tó tóbi jù (34-40)

  • Ṣé ọmọ Dáfídì ni Kristi? (41-46)

 • 23

  • Ẹ má tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí (1-12)

  • Àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí gbé (13-36)

  • Jésù dárò lórí Jerúsálẹ́mù (37-39)

 • 24

  • ÀMÌ PÉ JÉSÙ TI WÀ NÍHÌN-ÍN (1-51)

   • Ogun, àìtó oúnjẹ, ìmìtìtì ilẹ̀ (7)

   • A máa wàásù ìhìn rere (14)

   • Ìpọ́njú ńlá (21, 22)

   • Àmì Ọmọ èèyàn (30)

   • Igi ọ̀pọ̀tọ́ (32-34)

   • Bí ọjọ́ Nóà ṣe rí (37-39)

   • Ẹ máa ṣọ́nà (42-44)

   • Ẹrú olóòótọ́ àti ẹrú burúkú (45-51)

 • 25

  • ÀMÌ PÉ JÉSÙ TI WÀ NÍHÌN-ÍN (1-46)

   • Àpèjúwe àwọn wúńdíá mẹ́wàá (1-13)

   • Àpèjúwe tálẹ́ńtì (14-30)

   • Àwọn àgùntàn àti ewúrẹ́ (31-46)

 • 26

  • Àwọn àlùfáà gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù (1-5)

  • Ó da òróró onílọ́fínńdà sára Jésù (6-13)

  • Ìrékọjá tó gbẹ̀yìn àti ẹni tó máa da Jésù (14-25)

  • Jésù fi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa lọ́lẹ̀ (26-30)

  • Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (31-35)

  • Jésù gbàdúrà ní Gẹ́tísémánì (36-46)

  • Wọ́n mú Jésù (47-56)

  • Wọ́n gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (57-68)

  • Pétérù sẹ́ Jésù (69-75)

 • 27

  • Wọ́n fa Jésù lé Pílátù lọ́wọ́ (1, 2)

  • Júdásì pokùnso (3-10)

  • Jésù dé iwájú Pílátù (11-26)

  • Wọ́n fi ṣẹlẹ́yà ní gbangba (27-31)

  • Wọ́n kàn án mọ́gi ní Gọ́gọ́tà (32-44)

  • Ikú Jésù (45-56)

  • Wọ́n sìnkú Jésù (57-61)

  • Wọ́n sé ibojì rẹ̀ mọ́ (62-66)

 • 28

  • Jésù jíǹde (1-10)

  • Àwọn ọmọ ogun gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n lè purọ́ (11-15)

  • Ó pàṣẹ pé ká sọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn (16-20)