Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àkọsílẹ̀ Ìhìn Rere Máàkù

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

 • 1

  • Jòhánù Onírìbọmi ń wàásù (1-8)

  • Jésù ṣèrìbọmi (9-11)

  • Sátánì dán Jésù wò (12, 13)

  • Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù ní Gálílì (14, 15)

  • Ó pe àwọn tó kọ́kọ́ di ọmọ ẹ̀yìn (16-20)

  • Ó lé ẹ̀mí àìmọ́ jáde (21-28)

  • Jésù wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn ní Kápánáúmù (29-34)

  • Ó gbàdúrà níbi tó dá (35-39)

  • Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn (40-45)

 • 2

  • Jésù wo alárùn rọpárọsẹ̀ sàn (1-12)

  • Jésù pe Léfì (13-17)

  • Wọ́n béèrè nípa ààwẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ (18-22)

  • Jésù ni “Olúwa Sábáàtì” (23-28)

 • 3

  • Ó wo ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ sàn (1-6)

  • Èrò rẹpẹtẹ wá sí èbúté (7-12)

  • Àwọn àpọ́sítélì méjìlá (13-19)

  • Ọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́ (20-30)

  • Ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀ (31-35)

 • 4

  • ÀWỌN ÀPÉJÚWE NÍPA ÌJỌBA NÁÀ (1-34)

   • Afúnrúgbìn (1-9)

   • Ìdí tí Jésù fi lo àwọn àpèjúwe (10-12)

   • Ó ṣàlàyé ìtumọ̀ àpèjúwe afúnrúgbìn (13-20)

   • A kì í gbé fìtílà sábẹ́ apẹ̀rẹ̀ (21-23)

   • Òṣùwọ̀n tí ẹ fi ń díwọ̀n (24, 25)

   • Afúnrúgbìn tó sùn (26-29)

   • Hóró músítádì (30-32)

   • Ó ń lo àpèjúwe (33, 34)

  • Jésù mú kí ìjì dáwọ́ dúró (35-41)

 • 5

  • Jésù lé àwọn ẹ̀mí èṣù lọ sínú ẹlẹ́dẹ̀ (1-20)

  • Ọmọbìnrin Jáírù; obìnrin kan fọwọ́ kan aṣọ àwọ̀lékè Jésù (21-43)

 • 6

  • Wọn ò tẹ́wọ́ gba Jésù ní ìlú rẹ̀ (1-6)

  • Ó fún àwọn Méjìlá náà ní ìtọ́ni nípa iṣẹ́ ìwàásù (7-13)

  • Wọ́n pa Jòhánù Onírìbọmi (14-29)

  • Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (30-44)

  • Jésù rìn lórí omi (45-52)

  • Ó ṣe ìwòsàn ní Jẹ́nẹ́sárẹ́tì (53-56)

 • 7

  • Ó tú àṣírí àwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ àwọn èèyàn (1-13)

  • Inú ọkàn ni ohun tó ń sọni di aláìmọ́ ti ń wá (14-23)

  • Ìgbàgbọ́ obìnrin tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Foníṣíà ní Síríà (24-30)

  • Ó wo adití sàn (31-37)

 • 8

  • Jésù bọ́ 4,000 èèyàn (1-9)

  • Wọ́n béèrè àmì (10-13)

  • Ìwúkàrà àwọn Farisí àti ti Hẹ́rọ́dù (14-21)

  • Ó wo afọ́jú kan sàn ní Bẹtisáídà (22-26)

  • Pétérù pè é ní Kristi (27-30)

  • Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú Jésù (31-33)

  • Ojúlówó ọmọ ẹ̀yìn (34-38)

 • 9

  • A yí Jésù pa dà di ológo (1-13)

  • Ó wo ọmọkùnrin tí ẹ̀mí èṣù ń yọ lẹ́nu sàn (14-29)

   • Ohun gbogbo ṣeé ṣe fún ẹni tó ní ìgbàgbọ́ (23)

  • Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (30-32)

  • Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń jiyàn nípa ẹni tó tóbi jù (33-37)

  • Ẹni tí kò bá ta kò wá, tiwa ló ń ṣe (38-41)

  • Àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀ (42-48)

  • “Ẹ ní iyọ̀ nínú ara yín” (49, 50)

 • 10

  • Ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ (1-12)

  • Jésù súre fún àwọn ọmọdé (13-16)

  • Ìbéèrè ọkùnrin ọlọ́rọ̀ (17-25)

  • Àwọn ohun tí a yááfì torí Ìjọba náà (26-31)

  • Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (32-34)

  • Ohun tí Jémíìsì àti Jòhánù béèrè (35-45)

   • Jésù fi ẹ̀mí rẹ̀ ṣe ìràpadà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn (45)

  • Ó wo Báátíméù afọ́jú sàn (46-52)

 • 11

  • Jésù gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọnú ìlú (1-11)

  • Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́ (12-14)

  • Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (15-18)

  • Ohun tí a rí kọ́ lára igi ọ̀pọ̀tọ́ tó rọ (19-26)

  • Wọ́n béèrè ẹni tó fún Jésù ní àṣẹ (27-33)

 • 12

  • Àpèjúwe àwọn tó ń dáko tí wọ́n sì pààyàn (1-12)

  • Ọlọ́run àti Késárì (13-17)

  • Ìbéèrè nípa àjíǹde (18-27)

  • Àṣẹ méjì tó tóbi jù (28-34)

  • Ṣé ọmọ Dáfídì ni Kristi? (35-37a)

  • Ó ní kí wọ́n ṣọ́ra fún àwọn akọ̀wé òfin (37b-40)

  • Opó aláìní fi ẹyọ owó méjì sílẹ̀ (41-44)

 • 13

  • ÌPARÍ È ÀWỌN NǸKAN (1-37)

   • Ogun, ìmìtìtì ilẹ̀, àìtó oúnjẹ (8)

   • A máa wàásù ìhìn rere (10)

   • Ìpọ́njú ńlá (19)

   • Ọmọ èèyàn ń bọ̀ (26)

   • Àpèjúwe igi ọ̀pọ̀tọ́ (28-31)

   • Ẹ máa ṣọ́nà (32-37)

 • 14

  • Àwọn àlùfáà gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù (1, 2)

  • Ó da òróró onílọ́fínńdà sórí Jésù (3-9)

  • Júdásì da Jésù (10, 11)

  • Ìrékọjá tó gbẹ̀yìn (12-21)

  • Jésù fi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa lọ́lẹ̀ (22-26)

  • Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (27-31)

  • Jésù gbàdúrà ní Gẹ́tísémánì (32-42)

  • Wọ́n mú Jésù (43-52)

  • Wọ́n gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (53-65)

  • Pétérù sẹ́ Jésù (66-72)

 • 15

  • Jésù dé iwájú Pílátù (1-15)

  • Wọ́n fi ṣẹlẹ́yà ní gbangba (16-20)

  • Wọ́n kàn án mọ́gi ní Gọ́gọ́tà (21-32)

  • Ikú Jésù (33-41)

  • Wọ́n sìnkú Jésù (42-47)

 • 16

  • Jésù jíǹde (1-8)