Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àkọsílẹ̀ Ìhìn Rere Lúùkù

Orí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

 • 1

  • Ó kọ̀wé sí Tìófílọ́sì (1-4)

  • Gébúrẹ́lì sọ tẹ́lẹ̀ pé wọ́n máa bí Jòhánù Arinibọmi (5-25)

  • Gébúrẹ́lì sọ tẹ́lẹ̀ pé wọ́n máa bí Jésù (26-38)

  • Màríà lọ kí Èlísábẹ́tì (39-45)

  • Màríà gbé Jèhófà ga (46-56)

  • Wọ́n bí Jòhánù, wọ́n sì sọ ọ́ lórúkọ (57-66)

  • Sekaráyà sọ tẹ́lẹ̀ (67-80)

 • 2

  • Wọ́n bí Jésù (1-7)

  • Àwọn áńgẹ́lì yọ sí àwọn olùṣọ́ àgùntàn (8-20)

  • Ìdádọ̀dọ́ àti ìwẹ̀mọ́ (21-24)

  • Síméónì rí Kristi (25-35)

  • Ánà sọ̀rọ̀ ọmọ náà (36-38)

  • Wọ́n pa dà sí Násárẹ́tì (39, 40)

  • Jésù ọmọ ọdún méjìlá wà nínú tẹ́ńpìlì (41-52)

 • 3

  • Ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Jòhánù (1, 2)

  • Jòhánù ń wàásù pé kí wọ́n ṣèrìbọmi (3-20)

  • Jésù ṣèrìbọmi (21, 22)

  • Ìlà ìdílé Jésù Kristi (23-38)

 • 4

  • Èṣù dán Jésù wò (1-13)

  • Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù ní Gálílì (14, 15)

  • Wọn ò tẹ́wọ́ gba Jésù ní Násárẹ́tì (16-30)

  • Nínú sínágọ́gù ní Kápánáúmù (31-37)

  • Ó wo ìyá ìyàwó Símónì àtàwọn míì sàn (38-41)

  • Àwọn èrò rí Jésù ní ibi tó dá (42-44)

 • 5

  • Wọ́n rí ẹja kó lọ́nà ìyanu; àwọn ọmọ ẹ̀yìn àkọ́kọ́ (1-11)

  • Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn (12-16)

  • Jésù wo alárùn rọpárọsẹ̀ sàn (17-26)

  • Jésù pe Léfì (27-32)

  • Ìbéèrè nípa ààwẹ̀ (33-39)

 • 6

  • Jésù ni “Olúwa Sábáàtì” (1-5)

  • Ó wo ọkùnrin kan tí ọwọ́ rẹ̀ rọ sàn (6-11)

  • Àwọn àpọ́sítélì méjìlá (12-16)

  • Jésù ń kọ́ni, ó sì ń woni sàn (17-19)

  • Àwọn aláyọ̀ àtàwọn tí a káàánú wọn (20-26)

  • Nífẹ̀ẹ́ àwọn ọ̀tá (27-36)

  • Ẹ má ṣe dáni lẹ́jọ́ mọ́ (37-42)

  • Èso igi la fi ń mọ̀ ọ́n (43-45)

  • Ilé tí wọ́n kọ́ dáadáa; ilé tí ìpìlẹ̀ rẹ̀ ò lágbára (46-49)

 • 7

  • Ìgbàgbọ́ ọ̀gágun (1-10)

  • Jésù jí ọmọkùnrin opó Náínì dìde (11-17)

  • Ó yin Jòhánù Arinibọmi (18-30)

  • Ó dá ìran ọlọ́kàn líle lẹ́bi (31-35)

  • Ó dárí ji obìnrin kan tó jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ (36-50)

   • Àpèjúwe àwọn tó jẹ gbèsè (41-43)

 • 8

  • Àwọn obìnrin tó ń tẹ̀ lé Jésù (1-3)

  • Àpèjúwe afúnrúgbìn (4-8)

  • Ìdí tí Jésù fi ń lo àwọn àpèjúwe (9, 10)

  • Ó ṣàlàyé àpèjúwe afúnrúgbìn (11-15)

  • A kì í bo fìtílà mọ́lẹ̀ (16-18)

  • Ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀ (19-21)

  • Jésù mú kí ìjì dáwọ́ dúró (22-25)

  • Jésù lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde sínú ẹlẹ́dẹ̀ (26-39)

  • Ọmọbìnrin Jáírù; obìnrin kan fọwọ́ kan aṣọ àwọ̀lékè Jésù (40-56)

 • 9

  • Ó fún àwọn Méjìlá náà ní ìtọ́ni nípa iṣẹ́ ìwàásù (1-6)

  • Ìdààmú bá Hẹ́rọ́dù torí Jésù (7-9)

  • Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (10-17)

  • Pétérù pè é ní Kristi (18-20)

  • Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú Jésù (21, 22)

  • Ojúlówó ọmọ ẹ̀yìn (23-27)

  • A yí Jésù pa dà di ológo (28-36)

  • Ó wo ọmọkùnrin tí ẹ̀mí èṣù ń yọ lẹ́nu sàn (37-43a)

  • Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀  (43b-45)

  • Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń jiyàn nípa ẹni tó tóbi jù (46-48)

  • Ẹni tí kò bá ta kò wá, tiwa ló ń ṣe (49, 50)

  • Àwọn ará abúlé kan ní Samáríà kọ Jésù (51-56)

  • Bí a ṣe lè tẹ̀ lé Jésù (57-62)

 • 10

  • Jésù rán 70 èèyàn jáde (1-12)

  • Àwọn ìlú tí kò ronú pìwà dà gbé (13-16)

  • Àwọn 70 náà pa dà dé (17-20)

  • Jésù yin Baba rẹ̀ torí ó ṣojúure sí àwọn onírẹ̀lẹ̀ (21-24)

  • Àpèjúwe ará Samáríà tó jẹ́ aládùúgbò rere (25-37)

  • Jésù lọ sọ́dọ̀ Màtá àti Màríà (38-42)

 • 11

  • Bí o ṣe lè gbàdúrà (1-13)

   • Àdúrà àwòkọ́ṣe (2-4)

  • Ó fi ìka Ọlọ́run lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde (14-23)

  • Ẹ̀mí àìmọ́ pa dà wá (24-26)

  • Ayọ̀ tòótọ́ (27, 28)

  • Àmì Jónà (29-32)

  • Fìtílà ara (33-36)

  • Àwọn ẹlẹ́sìn tó ń ṣe àgàbàgebè gbé (37-54)

 • 12

  • Ìwúkàrà àwọn Farisí (1-3)

  • Bẹ̀rù Ọlọ́run, má bẹ̀rù èèyàn (4-7)

  • Fi hàn pé o wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi (8-12)

  • Àpèjúwe ọkùnrin ọlọ́rọ̀ kan tó jẹ́ òmùgọ̀ (13-21)

  • Ẹ yéé ṣàníyàn (22-34)

   • Agbo kékeré (32)

  • Ṣíṣọ́nà (35-40)

  • Ìríjú olóòótọ́ àti ìríjú aláìṣòótọ́ (41-48)

  • Kì í ṣe àlàáfíà, ìpínyà ni (49-53)

  • Ó yẹ kí wọ́n ṣàyẹ̀wò àkókò (54-56)

  • Yíyanjú ọ̀rọ̀ (57-59)

 • 13

  • Ẹ ronú pìwà dà àbí kí ẹ pa run (1-5)

  • Àpèjúwe igi ọ̀pọ̀tọ́ tí kò so èso (6-9)

  • Ó ṣèwòsàn fún obìnrin tí ẹ̀yìn rẹ̀ tẹ̀ ní Sábáàtì (10-17)

  • Àpèjúwe hóró músítádì àti ìwúkàrà (18-21)

  • Ó gba ìsapá láti gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé (22-30)

  • Hẹ́rọ́dù, “kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ yẹn” (31-33)

  • Jésù dárò lórí Jerúsálẹ́mù (34, 35)

 • 14

  • Ó wo ọkùnrin kan tí ara rẹ̀ wú sàn ní Sábáàtì (1-6)

  • Jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ tí o bá jẹ́ àlejò (7-11)

  • Pe àwọn tí kò lè san án pa dà fún ọ (12-14)

  • Àpèjúwe àwọn àlejò tó ṣàwáwí (15-24)

  • Ohun tó máa ná ẹni tó bá fẹ́ jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn (25-33)

  • Iyọ̀ tí ò lágbára mọ́ (34, 35)

 • 15

  • Àpèjúwe àgùntàn tó sọ nù (1-7)

  • Àpèjúwe ẹyọ owó tó sọ nù (8-10)

  • Àpèjúwe ọmọ tó sọ nù (11-32)

 • 16

  • Àpèjúwe ìríjú aláìṣòdodo (1-13)

   • “Ẹni tó bá jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun tó kéré jù jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun tó pọ̀” (10)

  • Òfin àti Ìjọba Ọlọ́run (14-18)

  • Àpèjúwe ọkùnrin ọlọ́rọ̀ àti Lásárù (19-31)

 • 17

  • Ìkọ̀sẹ̀, ìdáríjì àti ìgbàgbọ́ (1-6)

  • Àwọn ẹrú tí kò dáa fún ohunkóhun (7-10)

  • Ó wo adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá sàn (11-19)

  • Dídé Ìjọba Ọlọ́run (20-37)

   • Ìjọba Ọlọ́run wà “ní àárín yín” (21)

   • “Ẹ rántí aya Lọ́ọ̀tì” (32)

 • 18

  • Àpèjúwe opó tí kò juwọ́ sílẹ̀ (1-8)

  • Farisí àti agbowó orí (9-14)

  • Jésù àti àwọn ọmọdé (15-17)

  • Alákòóso kan tó jẹ́ ọlọ́rọ̀ béèrè ìbéèrè (18-30)

  • Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (31-34)

  • Alágbe kan tó fọ́jú pa dà ríran (35-43)

 • 19

  • Jésù lọ sọ́dọ̀ Sákéù (1-10)

  • Àpèjúwe mínà mẹ́wàá (11-27)

  • Jésù gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọnú ìlú (28-40)

  • Jésù sunkún lórí Jerúsálẹ́mù (41-44)

  • Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (45-48)

 • 20

  • Wọ́n béèrè àṣẹ tí Jésù fi ń ṣe nǹkan (1-8)

  • Àpèjúwe àwọn tó ń dáko, tí wọ́n sì pààyàn (9-19)

  • Ọlọ́run àti Késárì (20-26)

  • Ìbéèrè nípa àjíǹde (27-40)

  • Ṣé ọmọ Dáfídì ni Kristi? (41-44)

  • Ó kìlọ̀ fún wọn nípa àwọn akọ̀wé òfin (45-47)

 • 21

  • Ẹyọ owó méjì tí opó aláìní fi sílẹ̀ (1-4)

  • ÀMÌ OHUN TÓ MÁA ṢẸLẸ̀ (5-36)

   • Ogun, ìmìtìtì ilẹ̀, àjàkálẹ̀ àrùn, àìtó oúnjẹ (10, 11)

   • Àwọn ọmọ ogun máa yí Jerúsálẹ́mù ká (20)

   • Àkókò tí a yàn fún àwọn orílẹ̀-èdè (24)

   • Ọmọ èèyàn ń bọ̀ (27)

   • Àpèjúwe igi ọ̀pọ̀tọ́ (29-33)

   • Ẹ wà lójúfò (34-36)

  • Jésù ń kọ́ni nínú tẹ́ńpìlì (37, 38)

 • 22

  • Àwọn àlùfáà gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù (1-6)

  • Wọ́n múra Ìrékọjá tó gbẹ̀yìn sílẹ̀ (7-13)

  • Jésù fi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa lọ́lẹ̀ (14-20)

  • “Èmi àti ẹni tó máa dà mí jọ wà lórí tábìlì” (21-23)

  • Wọ́n bára wọn jiyàn gidigidi nípa ẹni tó tóbi jù (24-27)

  • Jésù bá wọn dá májẹ̀mú ìjọba (28-30)

  • Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (31-34)

  • Ìdí tó fi yẹ kí wọ́n múra sílẹ̀; idà méjì (35-38)

  • Àdúrà Jésù lórí Òkè Ólífì (39-46)

  • Wọ́n mú Jésù (47-53)

  • Pétérù sẹ́ Jésù (54-62)

  • Wọ́n fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́ (63-65)

  • Wọ́n gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (66-71)

 • 23

  • Jésù wà níwájú Pílátù àti Hẹ́rọ́dù (1-25)

  • Wọ́n kan Jésù àti àwọn ọ̀daràn méjì mọ́gi (26-43)

   • “O máa wà pẹ̀lú mi ní Párádísè” (43)

  • Ikú Jésù (44-49)

  • Wọ́n sìnkú Jésù (50-56)

 • 24

  • Jésù jíǹde (1-12)

  • Lójú ọ̀nà tó lọ sí Ẹ́máọ́sì (13-35)

  • Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn (36-49)

  • Jésù pa dà sí ọ̀run (50-53)