BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018)

Jóẹ́lì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Yorùbá
Jóẹ́lì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg
nwt Jóẹ́lì ojú ìwé 1235

Ìwé Jóẹ́lì

Orí

1 2 3

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Àwọn kòkòrò ṣọṣẹ́ gan-an (1-14)

    • “Ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé” (15-20)

      • Wòlíì náà ké pe Jèhófà (19, 20)

  • 2

    • Ọjọ́ Jèhófà àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ (1-11)

    • Ìkésíni láti pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà (12-17)

      • “Ọkàn yín ni kí ẹ fà ya” (13)

    • Ohun tí Jèhófà sọ fún àwọn èèyàn rẹ̀ (18-32)

      • “Èmi yóò tú ẹ̀mí mi” (28)

      • Àwọn ohun ìyanu lójú ọ̀run àti ní ayé (30)

      • Àwọn tó ń ké pe orúkọ Jèhófà yóò rí ìgbàlà (32)

  • 3

    • Jèhófà dá gbogbo orílẹ̀-èdè lẹ́jọ́ (1-17)

      • Àfonífojì Jèhóṣáfátì (2, 12)

      • Àfonífojì ìpinnu (14)

      • Jèhófà jẹ́ odi ààbò Ísírẹ́lì (16)

    • Jèhófà ń bù kún àwọn èèyàn rẹ̀ (18-21)