Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà sí Àwọn Ará Éfésù

Orí

1 2 3 4 5 6

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

 • 1

  • Ìkíni (1, 2)

  • Àwọn ìbùkún tẹ̀mí (3-7)

  • À ń kó ohun gbogbo jọ nínú Kristi (8-14)

   • “Iṣẹ́ àbójútó kan” ní àwọn àkókò tí a ti yàn (10)

   • A fi ẹ̀mí gbé èdìdì lé wọn gẹ́gẹ́ bí “àmì ìdánilójú” (13, 14)

  • Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Éfésù, ó sì gbàdúrà fún wọn (15-23)

 • 2

  • Ọlọ́run sọ wọ́n di ààyè pẹ̀lú Kristi (1-10)

  • A wó ògiri tó pààlà (11-22)

 • 3

  • Àwọn Kèfèrí wọnú àṣírí mímọ́ (1-13)

   • Àwọn Kèfèrí di ajùmọ̀jogún pẹ̀lú Kristi (6)

   • Ìpinnu ayérayé Ọlọ́run (11)

  • Àdúrà pé kí àwọn ará Éfésù ní òye (14-21)

 • 4

  • Ìṣọ̀kan nínú ara Kristi (1-16)

   • Àwọn ẹ̀bùn tí ó jẹ́ èèyàn (8)

  • Ìwà àtijọ́ àti ìwà tuntun (17-32)

 • 5

  • Ọ̀rọ̀ mímọ́ àti ìwà mímọ́ (1-5)

  • Ẹ máa rìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìmọ́lẹ̀ (6-14)

  • Ẹ máa kún fún ẹ̀mí (15-20)

   • Ẹ máa lo àkókò yín lọ́nà to dára jù lọ (16)

  • Ìmọ̀ràn fún àwọn ọkọ àti ìyàwó (21-33)

 • 6

  • Ìmọ̀ràn fún àwọn ọmọ àti òbí (1-4)

  • Ìmọ̀ràn fún àwọn ẹrú àti ọ̀gá (5-9)

  • Gbogbo ìhámọ́ra ogun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run (10-20)

  • Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (21-24)