Sáàmù 117:1, 2

  • Kí gbogbo orílẹ̀-èdè yin Jèhófà

    • Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí Ọlọ́run ní pọ̀ gan-an (2)

117  Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;+Ẹ gbé e ga, gbogbo ẹ̀yin èèyàn.*+  2  Nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tó ní sí wa pọ̀ gan-an;+Òtítọ́+ Jèhófà wà títí láé.+ Ẹ yin Jáà!*+

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

^ Tàbí “agbo ilé.”
^ Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.