BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018)

3 Jòhánù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Yorùbá
3 Jòhánù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg
nwt 3 Jòhánù ojú ìwé 1630

Lẹ́tà Jòhánù Kẹta

Orí

1

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • Ìkíni àti àdúrà (1-4)

  • Jòhánù gbóríyìn fún Gáyọ́sì (5-8)

  • Díótíréfè fẹ́ fi ara rẹ̀ ṣe olórí (9, 10)

  • Àwọn ará ròyìn Dímẹ́tíríù dáadáa (11, 12)

  • Ìbẹ̀wò tó fẹ́ ṣe àti ìkíni (13, 14)