Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà Kejì sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

 • 1

  • Ìkíni (1, 2)

  • Ọlọ́run ń tù wá nínú nínú gbogbo ìpọ́njú wa (3-11)

  • Ìrìn àjò Pọ́ọ̀lù yí pa dà (12-24)

 • 2

  • Ó ń wu Pọ́ọ̀lù láti mú kí wọ́n láyọ̀ (1-4)

  • Ẹlẹ́ṣẹ̀ tí wọ́n dárí jì, tí wọ́n sì gbà pa dà (5-11)

  • Pọ́ọ̀lù lọ sí Tíróásì àti Makedóníà (12, 13)

  • Iṣẹ́ òjíṣẹ́ jẹ́ ìjáde àwọn tó ń yọ ayọ̀ ìṣẹ́gun (14-17)

   • A kì í ṣe akirità ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (17)

 • 3

  • Lẹ́tà ìdámọ̀ràn (1-3)

  • Àwọn òjíṣẹ́ májẹ̀mú tuntun (4-6)

  • Ògo májẹ̀mú tuntun ta yọ (7-18)

 • 4

  • Ìmọ́lẹ̀ ìhìn rere (1-6)

   • Ojú inú àwọn aláìgbàgbọ́ fọ́ (4)

  • Ìṣúra nínú àwọn ohun èlò tí a fi amọ̀ ṣe (7-18)

 • 5

  • Gbígbé ibùgbé ọ̀run wọ̀ (1-10)

  • Iṣẹ́ òjíṣẹ́ ìpadàrẹ́ (11-21)

   • Ẹ̀dá tuntun (17)

   • Ikọ̀ fún Kristi (20)

 • 6

  • Kí a má ṣi inú rere Ọlọ́run lò (1, 2)

  • Bí iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ṣe rí (3-13)

  • Ẹ má fi àìdọ́gba so pọ̀ (14-18)

 • 7

  • Ká wẹ ara wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀gbin (1)

  • Inú Pọ́ọ̀lù dùn sí àwọn ará Kọ́ríńtì (2-4)

  • Títù mú ìròyìn rere wá (5-7)

  • Ìbànújẹ́ ní ọ̀nà Ọlọ́run àti ìrònúpìwàdà (8-16)

 • 8

  • Wọ́n kó ọrẹ jọ fún àwọn Kristẹni tó wà ní Jùdíà (1-15)

  • Wọ́n fẹ́ rán Títù lọ sí Kọ́ríńtì (16-24)

 • 9

  • Ó fún wọn níṣìírí láti máa fúnni (1-15)

   • Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ẹni tó ń fúnni pẹ̀lú ìdùnnú (7)

 • 10

  • Pọ́ọ̀lù gbèjà iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ (1-18)

   • Àwọn ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara (4, 5)

 • 11

  • Pọ́ọ̀lù àti àwọn àpọ́sítélì adára-má-kù-síbì-kan (1-15)

  • Àwọn ìṣòro Pọ́ọ̀lù bó ṣe jẹ́ àpọ́sítélì (16-33)

 • 12

  • Àwọn ìran tí Pọ́ọ̀lù rí (1-7a)

  • ‘Ẹ̀gún nínú ara’ Pọ́ọ̀lù (7b-10)

  • Àwọn àpọ́sítélì adára-má-kù-síbìkan ò sàn jù ú lọ (11-13)

  • Bí ọ̀rọ̀ àwọn ará Kọ́ríńtì ṣe jẹ Pọ́ọ̀lù lógún (14-21)

 • 13

  • Ìkìlọ̀ ìkẹyìn àti ọ̀rọ̀ ìyànjú (1-14)

   • “Ẹ máa dán ara yín wò bóyá ẹ wà nínú ìgbàgbọ́” (5)

   • Ẹ máa ṣe ìyípadà; ẹ máa ronú níṣọ̀kan (11)