Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà Jòhánù Kìíní

Orí

1 2 3 4 5

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

 • 1

  • Ọ̀rọ̀ ìyè (1-4)

  • Ká máa rìn nínú ìmọ́lẹ̀ (5-7)

  • Ìdí tó fi yẹ ká máa jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wa (8-10)

 • 2

  • Ó fi Jésù ṣe ẹbọ ìpẹ̀tù (1, 2)

  • Ká máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ (3-11)

   • Àṣẹ àtijọ́ àti àṣẹ tuntun (7, 8)

  • Ìdí tó fi kọ̀wé sí wọn (12-14)

  • Ẹ má ṣe nífẹ̀ẹ́ ayé (15-17)

  • Ìkìlọ̀ nípa aṣòdì sí Kristi (18-29)

 • 3

  • Ọmọ Ọlọ́run ni wá (1-3)

  • Àwọn ọmọ Ọlọ́run yàtọ̀ sí àwọn ọmọ Èṣù (4-12)

   • Jésù máa fọ́ àwọn iṣẹ́ Èṣù túútúú (8)

  •  Ẹ nífẹ̀ẹ́ ara yín (13-18)

  • Ọlọ́run ju ọkàn wa lọ (19-24)

 • 4

  • Ẹ dán àwọn ọ̀rọ̀ tó ní ìmísí wò (1-6)

  • Ẹ mọ Ọlọ́run, kí ẹ sì nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ (7-21)

   • “Ọlọ́run jẹ́ ìfẹ́” (8, 16)

   • Kò sí ìbẹ̀rù nínú ìfẹ́ (18)

 • 5

  • Ẹni tó bá gba Jésù gbọ́ ti ṣẹ́gun ayé (1-12)

   • Ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run túmọ̀ sí (3)

  • Ohun tó dá wa lójú nípa agbára tí àdúrà ní (13-17)

  • Ẹ máa ṣọ́ra nínú ayé tó burú (18-21)

   • Gbogbo ayé wà lábẹ́ agbára ẹni burúkú náà (19)