Yorùbá
Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png
nwt ojú ìwé 2-4

Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí

Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí

Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí

A Túmọ̀ Rẹ̀ Látinú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun ní Èdè Gẹ̀ẹ́sì

—Tí A Tún Ṣe Lọ́dún 2013—

“Ohun tí Jèhófà [יהוה, YHWH] Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘ . . .Wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun; àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí, wọn ò sì ní wá sí ọkàn.’”Àìsáyà 65:13, 17; tún wo 2 Pétérù 3:13.

Ó wà lódindi tàbí lápá kan ní èdè tó ju igba ó lé ọgọ́rin (280) lọ. Tí o bá fẹ́ rí gbogbo èdè tí a ti túmọ̀ rẹ̀ sí, lọ sórí ìkànnì www.jw.org/yo.

Àròpọ̀ Gbogbo Ẹ̀dà Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Tí A Ti Tẹ̀ Jáde:

247,913,053 Ẹ̀dà

A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2024

Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé ti àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Yoruba (nwt-YR)

Made in U.S.A.

900 Red Mills Road

Wallkill, NY 12589-5200 U.S.A.