Sáàmù 117:1, 2
117 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;+Ẹ gbóríyìn fún un, gbogbo ẹ̀yin agbo ìdílé.+
2 Nítorí pé inú rere rẹ̀ onífẹ̀ẹ́ sí wa jẹ́ alágbára ńlá;+Òótọ́+ Jèhófà sì wà fún àkókò tí ó lọ kánrin.Ẹ yin Jáà!+


Ṣé wàá fẹ́ láti ka àpilẹ̀kọ yìí ní èdè %%?
Àwọn Èdè: