Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

“Ta Ni Ó Wà ní Ìhà Ọ̀dọ̀ Jèhófà?”

Kéèyàn jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà lóòótọ́ yàtọ̀ sí kó máa wu èèyàn láti jẹ́ adúróṣinṣin sí Ọlọ́run tàbí kéèyàn máa sọ pé òun jẹ́ adúróṣinṣin sí i. Ìtàn tó wà nínú Bíbélì, ní Ẹ́kísódù orí 20, 24, 32 àti 34 ṣàlàyé ọ̀rọ̀ yìí.

Ó dá lórí Ẹ́kísódù 20:​1-7; 24:​3-18; 32:​1-35; 34:​1-14.