Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Jékọ́bù Nífẹ̀ẹ́ Àlàáfíà

Wàá rí bí Jékọ́bù ṣe sapá gan-an kí àlàáfíà lè wà láàárín òun àtàwọn míì. Ìtàn yìí dá lórí Jẹ́nẹ́sísì 26:12-24; 27:41–28:5; 29:16-29; 31:36-55; 32:13-20; 33:1-11.

O Tún Lè Wo

ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ TÓ O LÈ KỌ́ LÁTINÚ BÍBÉLÌ

Jékọ́bù Rí Ogún Gbà

Ísákì àti Rèbékà bí ìbejì, wọ́n sì sọ wọ́n ní Ísọ̀ àti Jékọ́bù. Torí pé Ísọ̀ ní àkọ́bí, òun ló yẹ kó gba ogún ìdílé wọn. Kí nìdí tó fi sọ ogún yẹn nù torí oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan péré?

ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ TÓ O LÈ KỌ́ LÁTINÚ BÍBÉLÌ

Jékọ́bù àti Ísọ̀ Parí Ìjà Wọn

Kí ni Jékọ́bù ṣe tó fi rí ìbùkún gbà lọ́dọ̀ áńgẹ́lì kan? Báwo ni òun àti Ísọ̀ ṣe parí ìjà wọn?