Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Jèhófà Nìkan Ṣoṣo Ni Ọlọ́run Tòótọ́

Ní ọgọ́rùn-ún ọdún kẹwàá Ṣáájú Sànmánì Kristẹni, ohun mánigbàgbé kan ṣẹlẹ̀ tó jẹ́ káyé mọ ìyàtọ̀ láàárín àwọn ẹni rere àtàwọn ẹni ibi. Àwọn aláìnígbàgbọ́, ọba wọn apẹ̀yìndà àtàwọn àlùfáà apààyàn ló yí Èlíjà ká, àmọ́ Èlíjà ò dá wà. Wo bí Jèhófà ṣe jẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ pé òun nìkan ṣoṣo ni Ọlọ́run tòótọ́ nígbà yẹn àti bó ṣe ń ṣe bẹ́ẹ̀ náà lónìí.

Ó dá lórí 1 Àwọn Ọba 16:29-​33; 1 Àwọn Ọba 17:​1-7; 1 Àwọn Ọba 18:17-​46; àti 1 Àwọn Ọba 19:​1-8.