Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Jèhófà Ń Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn

Wàá rí bí Jósẹ́fù ṣe fi hàn pé òun nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run àtàwọn míì bó tilẹ̀ jẹ́ pé nǹkan ò rọrùn fún ún, àti bó ṣe rí ọwọ́ ìfẹ́ Jèhófà lára ẹ̀ ní gbogbo àsìkò tó fi wà nínú ìṣòro. Bó ṣe wà nínú ìwé Jẹ́nẹ́sísì 37:1-36; 39:1–47:12.