“Jẹ́ Onígboyà àti Alágbára Kí O Sì Gbé Ìgbésẹ̀”!
Ó gba kéèyàn ní ìgbọ́kànlé nínú Jèhófà kó tó lè kojú àwọn ìṣòro. A máa rí bí ìgbọ́kànlé tí Dáfídì ní ṣe mú kó gbé ìgbésẹ̀.
A gbé e ka 1 Kíróníkà 28:1-20; 1 Sámúẹ́lì 16:1-23; 17:1-51
O Tún Lè Wo
ILÉ ÌṢỌ́
“Ti Jèhófà Ni Ìjà Ogun Náà”
Kí ló ran Dáfídì lọ́wọ́ láti pa Gòláyátì? Kí la rí kọ́ látinú ìtàn Dáfídì?
ILÉ ÌṢỌ́