Dáfídì Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà
Wàá rí bí Dáfídì ṣe fi sùúrù dúró de Jèhófà nígbà tí wọ́n hùwà àìdáa sí i. Ìtàn náà dá lórí 1 Sámúẹ́lì 24:2-15; 25:1-35; 26:2-12; Sáàmù 37:1-7
O Tún Lè Wo
FÌGBOYÀ ṢE OHUN TÍ ỌLỌ́RUN FẸ́
Dáfídì—Ó Nígboyà, Ó sì Ṣe Ohun Tó Tọ́
Ẹnì kan ṣẹ Dáfídì. Ohun kan wá ṣẹlẹ̀ tó mú kó rọrùn fún un láti gbẹ̀san, àmọ́ kò ṣe bẹ́ẹ̀. Kí nìdí tí kò fi gbẹ̀san? Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ẹ̀?
FÌGBOYÀ ṢE OHUN TÍ ỌLỌ́RUN FẸ́
Ábígẹ́lì—Ó Yanjú Ìṣòro Ńlá Kan
Kí làwọn aya àtàwọn ọkọ lè kọ́ látinú ìtàn Ábígẹ́lì?
ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ TÓ O LÈ KỌ́ LÁTINÚ BÍBÉLÌ
Dáfídì àti Sọ́ọ̀lù
Kí nìdí tí ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin yìí fi kórìíra ìkejì, báwo ni ìkejì ṣe hùwà sí èyí tó kórìíra rẹ̀?
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Ábígẹ́lì Hùwà Ọlọgbọ́n
Kí la rí kọ́ látinú bí ilé ọkọ kò ṣe rọrùn fún Ábígẹ́lì?

