Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Omi

Omi

Ní gbogbo ọ̀nà ni omi fi wúlò fún gbogbo ohun alààyè. Látorí ẹ̀kán omi títí dórí alagbalúgbú òkun, pàtàkì ni omi jẹ́ nínú gbogbo ohun tó ń gbé ẹ̀mí ró.